current location : Lyricf.com
/
Songs
/
Becky from the Block [Yoruba translation]
Becky from the Block [Yoruba translation]
turnover time:2024-11-18 18:26:33
Becky from the Block [Yoruba translation]

Inglewood

Inglewood

Inglewood

[Akopo:]

Mi o ni duro titi tih mo fi ma doke

Emi nih Emi nih Becky lati igboro

Ko si ibi tih mo le lo, mo mo ibi ti mo ti wa

Mi o nih duro titi tih mo fi ma doke

Emi nih emi nih Becky lati block

Opo igba nih mo ma n ni di e sugbon mo fe pupo

Ko si ibi tih mo le lo mo mo ibi ti mo ti wa

(Verse mini:]

Yo, giradi Akoko, oak street alakobere

Ti ko jina sih Inglewood Cemetery

Mo GBE ninu igba iponju mo ranti

Mo wa ko lati ba igba lo bi igba ti mo n ka iwe itumo

Mo si n rin lo si Oja Kelso

Bo ti le je pe mo lanfaani ati rin Lori kapeti alawopupa

Idile mih gbe ninu ibi Igboko si Grandpa

Nitori mo bere si ni si se lati ran Baami lowo

Gbo gbo e bere nigba tih Grandpa soda soun

Nisi lojo kan emi na ma soda

Nisisiyi ko ju pe tani omobinrin yen?

Sugbon ni jokan mo wa wa ka kiri agbaye

Mo shi ma n wa ni ahamo, mo de ma duro

Mo shi ma n si se bimo tih wa ni irinajo

Nkan to dami loju nih pe mio nih sebi enikeni

Nkan to n shele niyen? Becky, Becky, Becky G

[Akope:]

Mi o ni duro titi tih mo fi ma doke

Emi nih Emi nih Becky lati igboro

Ko si ibi tih mo le lo, mo mo ibi ti mo ti wa

Mi o nih duro titi tih mo fi ma doke

Emi nih emi nih Becky lati block

Opo igba nih mo ma n ni di e sugbon mo fe pupo

Ko si ibi tih mo le lo mo mo ibi ti mo ti wa

[Verse keji:]

Yo, ki lo mo nipa wiwole ati ji jade ila?

Ki lo mo nipa wiwa 4×5?

Aiye mih n yipada kia kia loju mih

O ma n bami nigba tih mo ba wa ninu Hollywood ati Vine

To ba fe femi, O ni lo lati bere lowo baami

Ati awon aburo baami to je ogbon, wa pade won Lori oke

Lo jokan mo ka gbe Grammy wale

Sugbon bo ti wu kori mo ma gbe randies wale

Donuts, ati ki tun nih? Pemi to ba rimi

Emi shi nih B, bimo tun wa Lori mounmaworan

Mo shi n wo Is pelu okuta iyebiye ati ileke didan

O le mu mi jade nih abete mih, sugbon o ko le mu abete kuro ninu mih

Beeni mo feran Sushi mih, moferan calamari

Sugbon ko si oludana to daraju maami gangan lo

To ba le mumi yetutu ninu barrio mi

Mo wa pelu litas gbadura Rosario

Inglewood, Inglewood, Inglewood

[Akope:]

Mi o ni duro titi tih mo fi ma doke

Emi nih Emi nih Becky lati igboro

Ko si ibi tih mo le lo, mo mo ibi ti mo ti wa

Mi o nih duro titi tih mo fi ma doke

Emi nih emi nih Becky lati block

Opo igba nih mo ma n ni di e, sugbon mo fe pupo

Ko si ibi tih mo le lo mo mo ibi ti mo ti wa

Mi o ni duro titi tih mo fi ma doke

Emi nih Emi nih Becky lati igboro

Ko si ibi tih mo le lo, mo mo ibi ti mo ti wa

Mi o nih duro titi tih mo fi ma doke

Emi nih emi nih Becky lati block

Opo igba nih mo ma n ni di e, sugbon mo fe pupo

Ko si ibi tih mo le lo mo mo ibi ti mo ti wa

Inglewood, obirin Cali titi aiye

Imoriri Jennifer Lopez

Eyin omo Latin e side

Iwo orun

Beni, Beni

L.A.!

Comments
Welcome to Lyricf comments! Please keep conversations courteous and on-topic. To fosterproductive and respectful conversations, you may see comments from our Community Managers.
Sign up to post
Sort by
Show More Comments
Becky G
  • country:United States
  • Languages:English, Spanish, Italian
  • Genre:Hip-Hop/Rap, Pop
  • Official site:http://www.iambeckyg.com/
  • Wiki:http://en.wikipedia.org/wiki/Becky_G
Becky G
Becky G Also Performed Pyrics
Latest update
Copyright 2023-2024 - www.lyricf.com All Rights Reserved